Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jobu 36:32-33 BIBELI MIMỌ (BM)

32. Ìkáwọ́ rẹ̀ ni mànàmáná wà,ó sì ń rán ààrá láti sán lu ohun tí ó bá fẹ́.

33. Ìró ààrá ń kéde bíbọ̀ rẹ̀,àwọn ẹran ọ̀sìn sì mọ̀ pé ó súnmọ́ tòsí.

Ka pipe ipin Jobu 36