Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jobu 35:1-3 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Elihu tún ń bá ọ̀rọ̀ rẹ̀ bọ̀, ó ní,

2. “Jobu, ṣé o rò pé ó tọ̀nà,kí o máa sọ pé, ‘Ọ̀nà mi tọ́ níwájú Ọlọrun?’

3. Kí o tún máa bèèrè pé, ‘Anfaani wo ni mo ní?Tabi kí ni mo fi sàn ju ẹni tí ó dẹ́ṣẹ̀ lọ?’

Ka pipe ipin Jobu 35