Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jobu 34:33 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣé yóo san ẹ̀san fún ọ lọ́nà tí ó tẹ́ ọ lọ́rùn,nítorí pé o kọ̀ ọ́?Nítorí ìwọ ni o gbọdọ̀ yan ohun tí ó bá wù ọ́, kì í ṣe èmi,nítorí náà, sọ èrò ọkàn rẹ fún wa.

Ka pipe ipin Jobu 34

Wo Jobu 34:33 ni o tọ