Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jobu 34:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọn á kú ikú òjijì, ní ọ̀gànjọ́ òru;á mi gbogbo eniyan jìgìjìgì, wọn a sì kú.Ikú á mú àwọn alágbára lọ láì jẹ́ pé eniyan fi ọwọ́ kàn wọ́n.

Ka pipe ipin Jobu 34

Wo Jobu 34:20 ni o tọ