Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jobu 31:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. “Mo ti bá ojú mi dá majẹmu;n óo ṣe wá máa wo wundia?

2. Kí ni yóo jẹ́ ìpín mi lọ́dọ̀ Ọlọrun lókè?Kí ni ogún mi lọ́dọ̀ Olodumare?

Ka pipe ipin Jobu 31