Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jobu 30:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. “Ṣugbọn nisinsinyii àwọn tí wọ́n kéré sí mi ń fi mí ṣe ẹlẹ́yà,àwọn tí baba wọn kò tó fi wé àwọn ajátí ń ṣọ́ agbo ẹran mi.

2. Kí ni anfaani agbára wọn fún mi,àwọn tí wọn kò lókun ninu?

Ka pipe ipin Jobu 30