Àwọn tí wọn ń kú lọ ń kérora ní ìgboro,àwọn tí a pa lára ń ké fún ìrànlọ́wọ́,ṣugbọn Ọlọrun kò fetísí adura wọn.