Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jobu 21:4-6 BIBELI MIMỌ (BM)

4. Ṣé eniyan ni mò ń bá rojọ́ ni?Kí ló dé tí n óo fi mú sùúrù?

5. Ẹ wò mí, kí ẹnu yà yín,kí ẹ sì fọwọ́ bo ẹnu.

6. Nígbà tí mo ro ohun tí ó dé bá mi,ẹ̀rù bà mí, mo sì wárìrì.

Ka pipe ipin Jobu 21