Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jobu 2:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí wọ́n rí Jobu ní ọ̀ọ́kán, wọn kò mọ̀ ọ́n mọ́. Ṣugbọn nígbà tí wọ́n súnmọ́ ọn tí wọ́n mọ̀ pé òun ni, wọ́n bú sẹ́kún, wọ́n fa aṣọ wọn ya, wọ́n sì ku eruku sórí.

Ka pipe ipin Jobu 2

Wo Jobu 2:12 ni o tọ