Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jobu 18:20-21 BIBELI MIMỌ (BM)

20. Ẹnu yóo ya àwọn ará ìwọ̀ oòrùn,ìwárìrì yóo sì mú àwọn ará ìlà oòrùn,nítorí ohun tí yóo ṣẹlẹ̀ sí i.

21. Dájúdájú bẹ́ẹ̀ ni ibùgbé ẹni ibi yóo rí,àní, ilé ẹni tí kò mọ Ọlọrun.”

Ka pipe ipin Jobu 18