Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jobu 12:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo wá di ẹlẹ́yà lójú àwọn ọ̀rẹ́ mi,èmi tí mò ń ké pe Ọlọrun,tí ó sì ń dá mi lóhùn;èmi tí mo jẹ́ olódodo ati aláìlẹ́bi,mo wá di ẹlẹ́yà.

Ka pipe ipin Jobu 12

Wo Jobu 12:4 ni o tọ