Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 9:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Ahọ́n wọn dàbí ọfà apanirun,wọ́n ń sọ̀rọ̀ ẹ̀tàn.Olukuluku ń sọ̀rọ̀ alaafia jáde lẹ́nu fún aládùúgbò rẹ̀,ṣugbọn ète ikú ni ó ń pa sí i ninu ọkàn rẹ̀.

Ka pipe ipin Jeremaya 9

Wo Jeremaya 9:8 ni o tọ