Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 9:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí ẹni kẹ́ ọrun ni wọ́n kẹ́ ahọ́n wọn,láti máa fọ́n irọ́ jáde bí ẹni ta ọfà;dípò òtítọ́ irọ́ ní ń gbilẹ̀ ní ilẹ̀ náà.OLUWA ní,“Wọ́n ń tinú ibi bọ́ sinu ibi,wọn kò sì mọ̀ èmi OLUWA.”

Ka pipe ipin Jeremaya 9

Wo Jeremaya 9:3 ni o tọ