Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 9:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn ẹni tí ó bá fẹ́ fọ́nnu,ohun tí ó lè máa fi fọ́nnu ni pé òun ní òyeati pé òun mọ̀ pé, èmi OLUWA ni OLUWA tí ń ṣe ẹ̀tọ́,tí sì ń fi ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ ati òdodo hàn lórí ilẹ̀ ayé;nítorí pé àwọn nǹkan bẹ́ẹ̀ ni mo ní inú dídùn sí.”

Ka pipe ipin Jeremaya 9

Wo Jeremaya 9:24 ni o tọ