Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 9:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí ikú ti dé ojú fèrèsé wa,ó ti wọ ààfin wa.Ikú ń pa àwọn ọmọde nígboro,ati àwọn ọdọmọkunrin ní gbàgede.”

Ka pipe ipin Jeremaya 9

Wo Jeremaya 9:21 ni o tọ