Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 8:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, n óo fi aya wọn fún ẹlòmíràn,n óo fi oko wọn fún àwọn tí yóo ṣẹgun wọn.Nítorí pé láti orí àwọn mẹ̀kúnnù,títí dé orí àwọn eniyan pataki pataki,gbogbo wọn ni wọ́n ń lépa èrè àjẹjù.Láti orí wolii títí kan alufaa, èké ni gbogbo wọn.

Ka pipe ipin Jeremaya 8

Wo Jeremaya 8:10 ni o tọ