Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 8:1 BIBELI MIMỌ (BM)

“Tó bá di ìgbà náà, wọn yóo kó egungun àwọn ọba Juda jáde kúrò ninu ibojì wọn, ati egungun àwọn ìjòyè ibẹ̀; ati ti àwọn alufaa, ati ti àwọn wolii, ati ti àwọn ará Jerusalẹmu.

Ka pipe ipin Jeremaya 8

Wo Jeremaya 8:1 ni o tọ