Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 7:31 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n kọ́ pẹpẹ Tofeti ní àfonífojì Hinomu, wọ́n ń sun àwọn ọmọkunrin ati àwọn ọmọbinrin wọn níná níbẹ̀. N kò pa irú àṣẹ bẹ́ẹ̀ fún wọn; irú nǹkan bẹ́ẹ̀ kò tilẹ̀ fi ìgbà kan sí lọ́kàn mi.

Ka pipe ipin Jeremaya 7

Wo Jeremaya 7:31 ni o tọ