Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 7:29 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ẹ gé irun orí yín dànù,ẹ lọ sọkún tẹ̀dùntẹ̀dùn lórí òkè,nítorí OLUWA ti kọ ìran yín sílẹ̀,ó ti fi ibinu ta ìran yín nù.

Ka pipe ipin Jeremaya 7

Wo Jeremaya 7:29 ni o tọ