Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 7:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Sibẹ wọn kò gbọ́ tèmi, wọn kò tẹ́tí sí mi. Kàkà bẹ́ẹ̀, oríkunkun ni wọ́n ń ṣe. Iṣẹ́ burúkú wọn ju ti àwọn baba ńlá wọn lọ.

Ka pipe ipin Jeremaya 7

Wo Jeremaya 7:26 ni o tọ