Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 7:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn wọn kò gbọ́ràn, wọn kò sì tẹ́tí sí mi. Wọ́n ń tẹ̀lé ìmọ̀ ara wọn, wọ́n ń ṣe oríkunkun, dípò kí wọ́n máa lọ siwaju, ẹ̀yìn ni wọ́n ń pada sí.

Ka pipe ipin Jeremaya 7

Wo Jeremaya 7:24 ni o tọ