Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 7:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Nisinsinyii, ẹ lọ sí ilé mi ní Ṣilo, níbi ìjọ́sìn mi àkọ́kọ́, kí ẹ sì wo ohun tí mo ṣe sí i, nítorí ìwà burúkú Israẹli, àwọn eniyan mi.

Ka pipe ipin Jeremaya 7

Wo Jeremaya 7:12 ni o tọ