Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 6:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí omi ṣé ń sun jáde ninu kànga,bẹ́ẹ̀ ni ibi ń sun ní Jerusalẹmu.Ìròyìn ìwà ipá ati ti jàgídíjàgan ń kọlura wọn ninu rẹ̀,àìsàn ati ìpalára ni à ń rí níbẹ̀ nígbà gbogbo.

Ka pipe ipin Jeremaya 6

Wo Jeremaya 6:7 ni o tọ