Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 6:16 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA ní,“Ẹ lọ dúró ní oríta kí ẹ wo òréré,ẹ bèèrè àwọn ọ̀nà àtijọ́,níbi tí ọ̀nà dáradára wà, kí ẹ sì máa tọ̀ ọ́.Kí ẹ lè ní ìsinmi.”Ṣugbọn wọ́n kọ̀, wọ́n ní,“A kò ní tọ ọ̀nà náà.”

Ka pipe ipin Jeremaya 6

Wo Jeremaya 6:16 ni o tọ