Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 52:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọwọ́ àwọn ọmọ ogun Kalidea tẹ Sedekaya ọba, wọ́n sì mú un lọ sọ́dọ̀ ọba Babiloni ní Ribila, ní ilẹ̀ Hamati, ọba Babiloni sì ṣe ìdájọ́ fún un.

Ka pipe ipin Jeremaya 52

Wo Jeremaya 52:9 ni o tọ