Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 52:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n lu odi ìlú, àwọn ọmọ ogun sì gba ibẹ̀ sá jáde lóru. Wọ́n gba ẹnu ọ̀nà tí ó wà láàrin àwọn odi meji tí ó wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ ọgbà ọba, bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àwọn ará Kalidea yí ìlú náà po, wọ́n bá dorí kọ apá ọ̀nà àfonífojì odò Jọdani.

Ka pipe ipin Jeremaya 52

Wo Jeremaya 52:7 ni o tọ