Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 52:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó sì mú ọ̀gágun tí ń ṣe àkóso àwọn ọmọ ogun, ati meje ninu àwọn aṣojú ọba tí wọn rí láàrin ìlú ati akọ̀wé olórí ogun tí ń kọ orúkọ àwọn eniyan sílẹ̀ fún ogun jíjà. Wọ́n tún kó ọgọta eniyan ninu àwọn ará ìlú tí wọn rí láàrin ìgboro.

Ka pipe ipin Jeremaya 52

Wo Jeremaya 52:25 ni o tọ