Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 52:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Òpó keji rí bákan náà pẹlu èso Pomegiranate. Mẹrindinlọgọrun-un ni àwọn èso Pomegiranate tí ó wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ kọ̀ọ̀kan; ọgọrun-un ni gbogbo èso Pomegiranate tí ó wà ní àyíká ẹ̀wọ̀n náà.

Ka pipe ipin Jeremaya 52

Wo Jeremaya 52:23 ni o tọ