Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 52:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Bàbà tí Solomoni fi ṣe òpó mejeeji ati agbada omi, pẹlu àwọn mààlúù idẹ mejeejila tí wọ́n gbé agbada náà dúró, ati àwọn ìtẹ́lẹ̀ tí Solomoni ọba ṣe fún ilé OLUWA kọjá wíwọ̀n.

Ka pipe ipin Jeremaya 52

Wo Jeremaya 52:20 ni o tọ