Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 52:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo àwọn ọmọ ogun Kalidea tí wọ́n wà pẹlu olórí àwọn tí ń ṣọ́ Nebukadinesari ọba wó gbogbo odi Jerusalẹmu lulẹ̀ patapata.

Ka pipe ipin Jeremaya 52

Wo Jeremaya 52:14 ni o tọ