Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 51:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Babiloni ṣubú lójijì, ó sì fọ́;ẹ sun ẹkún arò nítorí rẹ̀!Ẹ fi ìwọ̀ra pa á lára nítorí ìrora rẹ̀,bóyá ara rẹ̀ yóo yá.

Ka pipe ipin Jeremaya 51

Wo Jeremaya 51:8 ni o tọ