Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 51:62 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí ó sọ pé, “OLUWA, o ti sọ pé o óo pa ibí yìí run, tóbẹ́ẹ̀ tí kò fi ní sí nǹkankan tí yóo máa gbé inú rẹ̀ mọ́, ìbáà ṣe eniyan tabi ẹranko. O ní títí lae ni yóo di ahoro.”

Ka pipe ipin Jeremaya 51

Wo Jeremaya 51:62 ni o tọ