Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 51:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ sá kúrò láàrin Babiloni,kí olukuluku sá àsálà fún ẹ̀mí rẹ̀!Ẹ má parun nítorí ìjìyà ẹ̀ṣẹ̀ Babiloni;nítorí àkókò ẹ̀san OLUWA nìyí,yóo sì san ẹ̀san fún Babiloni.

Ka pipe ipin Jeremaya 51

Wo Jeremaya 51:6 ni o tọ