Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 51:58 BIBELI MIMỌ (BM)

Odi Babiloni tí ó fẹ̀, yóo wó lulẹ̀,a óo sì dáná sun àwọn ẹnubodè rẹ̀ tí ó ga fíofío.Iṣẹ́ lásán ni àwọn eniyan ń ṣe,àwọn orílẹ̀-èdè sì ń yọ ara wọn lẹ́nu lásán ni,nítorí pé iná yóo jó gbogbo làálàá wọn.”

Ka pipe ipin Jeremaya 51

Wo Jeremaya 51:58 ni o tọ