Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 51:30 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ ogun Babiloni ti ṣíwọ́ ogun jíjà,wọ́n wà ní ibi ààbò wọn;àárẹ̀ ti mú wọn, wọ́n sì ti di obinrin.Àwọn ilé inú rẹ̀ ti ń jóná,àwọn ọ̀pá ìdábùú ìlẹ̀kùn bodè rẹ̀ sì ti ṣẹ́.

Ka pipe ipin Jeremaya 51

Wo Jeremaya 51:30 ni o tọ