Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 51:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ pọ́n ọfà yín!Ẹ gbé asà yín!Nítorí OLUWA ti ru ẹ̀mí àwọn ọba Media sókè,nítorí pé ó ti pinnu láti pa Babiloni run.Ẹ̀san OLUWA ni, ẹ̀san nítorí tẹmpili rẹ̀ tí wọ́n wó.

Ka pipe ipin Jeremaya 51

Wo Jeremaya 51:11 ni o tọ