Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 50:39 BIBELI MIMỌ (BM)

“Nítorí náà àwọn ẹranko ìgbẹ́ ati ìkookò ni yóo máa gbé inú Babiloni, ẹyẹ ògòǹgò yóo máa gbé inú rẹ̀. Kò ní sí eniyan níbẹ̀, ẹnikẹ́ni kò ní gbé inú rẹ̀ mọ́ títí lae.

Ka pipe ipin Jeremaya 50

Wo Jeremaya 50:39 ni o tọ