Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 50:32 BIBELI MIMỌ (BM)

Agbéraga, o óo fẹsẹ̀ kọ, o óo sì ṣubú,kò ní sí ẹni tí yóo gbé ọ dìde.N óo dá iná kan ninu àwọn ìlú rẹ,iná náà yóo sì jó gbogbo àyíká rẹ.”

Ka pipe ipin Jeremaya 50

Wo Jeremaya 50:32 ni o tọ