Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 50:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo dẹ tàkúté sílẹ̀ fun yín, ẹ̀yin ará Babiloni:Tàkúté náà mu yín, ẹ kò sì mọ̀.Wọ́n ri yín, ọwọ́ sì tẹ̀ yín,nítorí pé ẹ yájú sí èmi OLUWA.

Ka pipe ipin Jeremaya 50

Wo Jeremaya 50:24 ni o tọ