Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 50:21 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA ní,“Ẹ gbógun ti ilẹ̀ Merataimu, ati àwọn ará Pekodi.Ẹ pa wọ́n, kí ẹ sì run wọ́n patapata.Gbogbo nǹkan tí mo pàṣẹ fun yín ni kí ẹ ṣe.Èmi OLUWA ni mo sọ bẹ́ẹ̀.

Ka pipe ipin Jeremaya 50

Wo Jeremaya 50:21 ni o tọ