Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 50:19 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo mú Israẹli pada sí ibùjẹ rẹ̀, yóo máa jẹ oúnjẹ tí ó bá hù lórí òkè Kamẹli ati ní agbègbè Baṣani, yóo sì tẹ́ ìfẹ́ ọkàn rẹ̀ lọ́rùn lórí òkè Efuraimu ati òkè Gileadi.

Ka pipe ipin Jeremaya 50

Wo Jeremaya 50:19 ni o tọ