Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 50:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Ohun ìní àwọn ará Kalidea yóo di ìkógun; gbogbo àwọn tí wọn yóo kó wọn lẹ́rù ni yóo kó ẹrù ní àkótẹ́rùn, Èmi OLUWA ni mo sọ bẹ́ẹ̀.”

Ka pipe ipin Jeremaya 50

Wo Jeremaya 50:10 ni o tọ