Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 5:28 BIBELI MIMỌ (BM)

wọ́n sanra, ara wọn sì ń dán.Ṣugbọn iṣẹ́ ibi wọn kò ní ààlà.Wọn kìí dá ẹjọ́ ẹ̀tọ́ fún aláìníbaba,kí ó lè rí ẹ̀tọ́ rẹ̀ gbà;wọn kò sì jẹ́ gbèjà aláìní,kí wọ́n bá a dáàbò bo ẹ̀tọ́ rẹ̀ nílé ẹjọ́.

Ka pipe ipin Jeremaya 5

Wo Jeremaya 5:28 ni o tọ