Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 5:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ wò ó, ẹ̀yin ọmọ ilé Israẹli,mò ń mú orílẹ̀-èdè kan bọ̀ wá ba yín, láti ilẹ̀ òkèèrè,tí yóo ba yín jà.Láti ayé àtijọ́ ni orílẹ̀-èdè ọ̀hún ti wà,orílẹ̀-èdè alágbára ni.Ẹ kò gbọ́ èdè wọn,ẹ kò sì ní mọ ohun tí wọ́n ń sọ.

Ka pipe ipin Jeremaya 5

Wo Jeremaya 5:15 ni o tọ