Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 5:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Máa sáré lọ, sáré bọ̀ ní àwọn òpópónà Jerusalẹmu,wò yíká, kí o sì ṣàkíyèsí rẹ̀!Wo àwọn gbàgede rẹ̀, bóyá o óo rí ẹnìkan,tí ó ń ṣe ìdájọ́ òdodo,tí ó sì ń fẹ́ òtítọ́,tí mo fi lè torí rẹ̀ dáríjì Jerusalẹmu.

Ka pipe ipin Jeremaya 5

Wo Jeremaya 5:1 ni o tọ