Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 49:37 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo dẹ́rùbà wọ́n; níwájú àwọn ọ̀tá wọn, ati níwájú àwọn tí ń wá ọ̀nà ati pa wọ́n. N óo bínú sí wọn gan-an, n óo sì mú kí ibi dé bá wọn. Èmi OLUWA ni mo sọ bẹ́ẹ̀. N óo rán ogun tẹ̀lé wọn, títí n óo fi pa wọ́n tán.

Ka pipe ipin Jeremaya 49

Wo Jeremaya 49:37 ni o tọ