Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 49:32 BIBELI MIMỌ (BM)

“Àwọn ràkúnmí ati agbo ẹran wọn yóo di ìkógun.N óo fọ́n àwọn tí wọn ń gé ẹsẹ̀ irun wọn ká sí igun mẹrẹẹrin ayé,n óo sì mú kí ibi bá wọn láti gbogbo àyíká wọn.

Ka pipe ipin Jeremaya 49

Wo Jeremaya 49:32 ni o tọ