Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 49:30 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ẹ̀yin ará Hasori, ẹ sá,ẹ lọ jìnnà réré, kí ẹ sì máa gbé inú ọ̀gbun.Nítorí pé Nebukadinesari, ọba Babiloni ń pète ibi si yín,ó ti pinnu ibi si yín.

Ka pipe ipin Jeremaya 49

Wo Jeremaya 49:30 ni o tọ