Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 49:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Ohun tí OLUWA sọ nípa Damasku nìyí, Ó ní,“Ìdààmú dé bá Hamati ati Aripadi,nítorí pé wọ́n gbọ́ ìròyìn burúkú:Jìnnìjìnnì dà bò wọ́n, ọkàn wọn sì dàrú,bí omi òkun tí kò lè dákẹ́ jẹ́ẹ́.

Ka pipe ipin Jeremaya 49

Wo Jeremaya 49:23 ni o tọ