Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 49:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Yóo rí fún un bí ó ti rí fún Sodomu ati Gomora ati àwọn ìlú agbègbè wọn tí ó parun. Ẹnikẹ́ni kò ní gbé ibẹ̀, bẹ́ẹ̀ ni ẹnikẹ́ni kò ní dé sibẹ. Èmi OLUWA ni mo sọ bẹ́ẹ̀.

Ka pipe ipin Jeremaya 49

Wo Jeremaya 49:18 ni o tọ